Owe 13:19 - Compare All Versions

Owe 13:19 YBCV (Bibeli Mimọ)

Ifẹ ti a muṣẹ dùnmọ ọkàn; ṣugbọn irira ni fun aṣiwere lati kuro ninu ibi.

Owe 13:19 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ìfẹ́ tí a mú ṣẹ dùn mọ́ ọkàn ṣùgbọ́n ìríra ni fún aṣiwèrè láti kúrò nínú ibi.

Owe 13:19 YCE (Yoruba Bible)

Bí èrò ọkàn ẹni bá ṣẹ, a máa fúnni láyọ̀, ṣugbọn àwọn òmùgọ̀ kórìíra ati kọ ibi sílẹ̀.