Owe 12:26
Owe 12:26 Yoruba Bible (YCE)
Olódodo a máa yipada kúrò ninu ibi, ṣugbọn ìwà ẹni ibi a máa mú un ṣìnà.
Pín
Kà Owe 12Owe 12:26 Bibeli Mimọ (YBCV)
Olododo tọ́ aladugbo rẹ̀ si ọ̀na; ṣugbọn ọ̀na awọn enia buburu tàn wọn jẹ.
Pín
Kà Owe 12