Owe 12:17
Owe 12:17 Yoruba Bible (YCE)
Ẹni tí ó bá ń sọ òtítọ́ a máa jẹ́rìí òdodo, ṣugbọn irọ́ ni ẹlẹ́rìí èké máa ń pa.
Pín
Kà Owe 12Owe 12:17 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹniti o sọ otitọ, o fi ododo hàn jade; ṣugbọn ẹlẹri eke, ẹ̀tan.
Pín
Kà Owe 12