Owe 10:23
Owe 10:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Aláìgbọ́n a máa ní inú dídùn sí ìwà búburú ṣùgbọ́n olóye ènìyàn a máa ní inú dídùn sí ọgbọ́n.
Pín
Kà Owe 10Owe 10:23 Bibeli Mimọ (YBCV)
Bi ẹrín ni fun aṣiwere lati hu ìwa-ika: ṣugbọn ọlọgbọ́n li ẹni oye.
Pín
Kà Owe 10