Owe 1:28-29
Owe 1:28-29 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nigbana ni ẹnyin o kepè mi, ṣugbọn emi kì yio dahùn; nwọn o ṣafẹri mi ni kùtukùtu, ṣugbọn nwọn kì yio ri mi: Nitori ti nwọn korira ìmọ, nwọn kò si yàn ibẹ̀ru Oluwa.
Pín
Kà Owe 1Nigbana ni ẹnyin o kepè mi, ṣugbọn emi kì yio dahùn; nwọn o ṣafẹri mi ni kùtukùtu, ṣugbọn nwọn kì yio ri mi: Nitori ti nwọn korira ìmọ, nwọn kò si yàn ibẹ̀ru Oluwa.