Filp 4:2
Filp 4:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Èmi ń bẹ̀ Euodia, mo sì ń bẹ Sintike, kí wọn ní inú kan náà nínú Olúwa.
Pín
Kà Filp 4Filp 4:2 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi mbẹ̀ Euodia, mo si mbẹ̀ Sintike, ki nwọn ni inu kanna ninu Oluwa.
Pín
Kà Filp 4