Filp 3:19
Filp 3:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ìgbẹ̀yìn wọn ni ìparun, ikùn wọn sì ni Ọlọ́run wọn, wọ́n sì ń ṣògo nínú ìtìjú wọn, àwọn ẹni tí ń tọ́jú ohun ti ayé.
Pín
Kà Filp 3Filp 3:19 Bibeli Mimọ (YBCV)
Igbẹhin ẹniti iṣe iparun, ikùn ẹniti iṣe ọlọrun wọn, ati ogo ẹniti o wà ninu itiju wọn, awọn ẹniti ntọju ohun aiye.)
Pín
Kà Filp 3