Filp 1:30
Filp 1:30 Yoruba Bible (YCE)
Irú ìyà kan náà tí ẹ rí ninu ìgbé-ayé mi, tí ẹ tún ń gbọ́ pé mò ń jẹ títí di àkókò yìí ni ẹ̀yin náà ń jẹ báyìí.
Pín
Kà Filp 1Filp 1:30 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ si ni ìja kanna ti ẹnyin ti ri ninu mi, ti ẹnyin si gbọ́ nisisiyi pe o wà ninu mi.
Pín
Kà Filp 1