Oba 1:21 - Compare All Versions
Oba 1:21 YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn olugbala yio si goke Sioni wá lati ṣe idajọ oke Esau; ijọba na yio si jẹ ti Oluwa.
Pín
Oba 1 YBCVOba 1:21 YCE (Yoruba Bible)
Àwọn olùgbàlà yóo lọ láti Sioni, wọn yóo jọba lórí òkè Edomu; ìjọba náà yóo sì jẹ́ ti OLUWA.”
Pín
Oba 1 YCEOba 1:21 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tó ń gba ni là yóò sì gòkè Sioni wá láti jẹ ọba lé orí àwọn òkè Esau. Ìjọba náà yóò sì jẹ́ ti OLúWA.
Pín
Oba 1 BMYO