Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Num 7:78BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ahira ọmọ Enani, olórí àwọn Naftali ni ó mú ọrẹ rẹ̀ wá ní ọjọ́ kejìlá.
Num 7:78YCE(Yoruba Bible)
Ní ọjọ́ kejila ni Ahira ọmọ Enani, olórí àwọn ẹ̀yà Nafutali, mú ọrẹ tirẹ̀ wá.