Num 6:24-26
Num 6:24-26 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ki OLUWA ki o busi i fun ọ, ki o si pa ọ mọ́: Ki OLUWA ki o mu oju rẹ̀ mọlẹ si ọ lara, ki o si ṣãnu fun ọ: Ki OLUWA ki o ma bojuwò ọ, ki o si ma fun ọ ni alafia.
Pín
Kà Num 6Num 6:24-26 Yoruba Bible (YCE)
‘Kí OLUWA bukun yín, kí ó sì pa yín mọ́. Kí OLUWA mú kí ojú rẹ̀ mọ́lẹ̀ sí yín lára, kí ó sì ṣàánú fún yín. Kí OLUWA bojúwò yín, kí ó sì fún yín ní alaafia.’
Pín
Kà Num 6