Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Num 33:2YBCV(Bibeli Mimọ)

Mose si kọwe ijadelọ wọn gẹgẹ bi ìrin wọn, nipa aṣẹ OLUWA; wọnyi si ni ìrin wọn gẹgẹ bi ijadelọ wọn.

Num 33:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Mose sì kọ̀wé ìjáde lọ wọn ní ẹsẹẹsẹ gẹ́gẹ́ bí ìrìnàjò wọn, nípa àṣẹ OLúWA, wọ̀nyí sì ni ìrìnàjò wọn gẹ́gẹ́ bí ìjáde lọ wọn.

Num 33:2YCE(Yoruba Bible)

(Orúkọ gbogbo ibi tí wọ́n pàgọ́ sí ni Mose ń kọ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àṣẹ OLUWA.)