Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Num 31:2YBCV(Bibeli Mimọ)
Gbẹsan awọn ọmọ Israeli lara awọn ara Midiani: lẹhin eyinì ni a o kó ọ jọ pẹlu awọn enia rẹ.
Pín
Num 31YBCVNum 31:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Gbẹ̀san lára àwọn Midiani fún àwọn ọmọ Israẹli. Lẹ́yìn ìgbà náà a ó kó ọ jọ pẹ̀lú àwọn ènìyàn rẹ.”
Pín
Num 31BMYONum 31:2YCE(Yoruba Bible)
“Fìyà jẹ àwọn ará Midiani fún ohun tí wọ́n ṣe sí àwọn ọmọ Israẹli. Lẹ́yìn náà, o óo kú.”
Pín
Num 31YCE