Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Num 3:7YBCV(Bibeli Mimọ)
Ki nwọn ki o ma pa aṣẹ rẹ̀ mọ́, ati aṣẹ gbogbo ajọ niwaju agọ́ ajọ, lati ṣe iṣẹ-ìsin agọ́.
Pín
Num 3YBCVNum 3:7BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn yóò máa ṣiṣẹ́ fún un àti fún gbogbo ìjọ ènìyàn ní àgọ́ ìpàdé bí wọ́n ti ń ṣiṣẹ́ ìsìn nínú àgọ́.
Pín
Num 3BMYONum 3:7YCE(Yoruba Bible)
Àwọn ni yóo máa ṣe iṣẹ́ iranṣẹ fún àwọn alufaa ati fún gbogbo ìjọ eniyan Israẹli níwájú Àgọ́ Àjọ bí àwọn alufaa tí ń ṣe iṣẹ́ níbi mímọ́.
Pín
Num 3YCE