Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Num 3:2YBCV(Bibeli Mimọ)
Wọnyi si li orukọ awọn ọmọ Aaroni; Nadabu akọ́bi, ati Abihu, Eleasari, ati Itamari.
Pín
Num 3YBCVNum 3:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Orúkọ àwọn ọmọ Aaroni nìwọ̀nyí, Nadabu ni àkọ́bí, Abihu, Eleasari àti Itamari.
Pín
Num 3BMYONum 3:2YCE(Yoruba Bible)
Orúkọ àwọn ọmọ Aaroni lọkunrin nìwọ̀nyí: Nadabu ni àkọ́bí, lẹ́yìn rẹ̀ ni Abihu, Eleasari ati Itamari.
Pín
Num 3YCE