Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Num 3:1YBCV(Bibeli Mimọ)
WỌNYI si li awọn iran Aaroni ati Mose li ọjọ́ ti OLUWA bá Mose sọ̀rọ li òke Sinai.
Pín
Num 3YBCVNum 3:1BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ̀nyí ni ìdílé Aaroni àti Mose ní ìgbà tí OLúWA bá Mose sọ̀rọ̀ ní òkè Sinai.
Pín
Num 3BMYONum 3:1YCE(Yoruba Bible)
Àwọn wọnyi ni ìdílé Aaroni ati ti Mose, nígbà tí OLUWA bá Mose sọ̀rọ̀ ní orí òkè Sinai.
Pín
Num 3YCE