Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Num 27:4YBCV(Bibeli Mimọ)
Ẽhaṣe ti orukọ, baba wa yio fi parẹ kuro ninu idile rẹ̀, nitoriti kò lí ọmọkunrin? Fun wa ni ilẹ-iní lãrin awọn arakunrin baba wa.
Pín
Num 27YBCVNum 27:4BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kín ni ó dé tí orúkọ baba wa yóò parẹ́ nínú ìdílé rẹ̀ nítorí pé kò ní ọmọkùnrin? Fún wa ní ilẹ̀ ìní láàrín àwọn arákùnrin baba wa.”
Pín
Num 27BMYONum 27:4YCE(Yoruba Bible)
Kí ló dé tí orúkọ baba wa yóo fi parẹ́ kúrò ninu ìdílé rẹ̀ nítorí pé kò ní ọmọkunrin? Nítorí náà, ẹ fún wa ní ilẹ̀ ìní láàrin àwọn eniyan baba wa.”
Pín
Num 27YCE