Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Num 26:65YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitoriti OLUWA ti wi fun wọn pe, Kíku ni nwọn o kú li aginjù. Kò si kù ọkunrin kan ninu wọn, bikoṣe Kalebu ọmọ Jefunne, ati Joṣua ọmọ Nuni.
Pín
Num 26YBCVNum 26:65BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí OLúWA ti sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé kíkú ni wọn yóò kú sí aginjù, kò sì sí ẹnìkankan nínú wọn tí kò kú àfi Kalebu ọmọ Jefunne, àti Joṣua ọmọ Nuni.
Pín
Num 26BMYONum 26:65YCE(Yoruba Bible)
Nítorí pé OLUWA ti sọ pé gbogbo àwọn ti ìgbà náà ni yóo kú ninu aṣálẹ̀. Kalebu ọmọ Jefune ati Joṣua ọmọ Nuni nìkan ni ó kù lára wọn.
Pín
Num 26YCE