Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Num 26:64YBCV(Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ninu wọnyi kò sì ọkunrin kan ninu awọn ti Mose ati Aaroni alufa kà, nigbati nwọn kà awọn ọmọ Israeli li aginjù Sinai.
Pín
Num 26YBCVNum 26:64BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kò sí ẹnìkan nínú àwọn tí Mose àti Aaroni àlùfáà kà nígbà tí wọ́n ka àwọn ọmọ Israẹli ní aginjù Sinai.
Pín
Num 26BMYONum 26:64YCE(Yoruba Bible)
Ṣugbọn kò sí ẹnìkan tí ó tíì dáyé ninu wọn nígbà tí Mose ati Aaroni alufaa, ka àwọn ọmọ Israẹli ní aṣálẹ̀ Sinai.
Pín
Num 26YCE