Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Num 26:1YBCV(Bibeli Mimọ)
O SI ṣe lẹhin àrun na, ni OLUWA sọ fun Mose ati fun Eleasari alufa ọmọ Aaroni pe
Pín
Num 26YBCVNum 26:1BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn àjàkálẹ̀-ààrùn OLúWA sọ fún Mose àti Eleasari ọmọ Aaroni, àlùfáà pé
Pín
Num 26BMYONum 26:1YCE(Yoruba Bible)
Lẹ́yìn àjàkálẹ̀ àrùn náà, OLUWA sọ fún Mose ati Eleasari alufaa ọmọ Aaroni pé
Pín
Num 26YCE