Num 22:29
Num 22:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Balaamu sọ fún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ pé, “Nítorí ìwọ fi mí ṣẹ̀sín! Bí mo bá ní idà ní ọwọ́ ni èmi ìbá pa ọ́ nísinsin yìí.”
Pín
Kà Num 22Num 22:29 Bibeli Mimọ (YBCV)
Balaamu si wi fun kẹtẹkẹtẹ na pe, Nitoriti iwọ fi mi ṣẹsin: idà iba wà li ọwọ́ mi, nisisiyi li emi iba pa ọ.
Pín
Kà Num 22