Num 14:28
Num 14:28 Yoruba Bible (YCE)
Nisinsinyii, sọ fún wọn pé, ‘Bí mo tì wà láàyè, n óo ṣe yín gẹ́gẹ́ bí ẹ ti wí.
Pín
Kà Num 14Num 14:28 Bibeli Mimọ (YBCV)
Wi fun wọn pe, OLUWA wipe, Bi mo ti wà nitõtọ, bi ẹnyin ti sọ li etí mi, bẹ̃li emi o ṣe si nyin
Pín
Kà Num 14