Num 13:1-2
Num 13:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
OLUWA si sọ fun Mose pe, Rán enia, ki nwọn ki o si ṣe amí ilẹ Kenaani, ti mo fi fun awọn ọmọ Israeli: ọkunrin kan ni ki ẹnyin ki o rán ninu ẹ̀ya awọn baba wọn, ki olukuluku ki o jẹ́ ijoye ninu wọn.
Pín
Kà Num 13