Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Num 11:2YBCV(Bibeli Mimọ)
Awọn enia na si kigbe tọ̀ Mose lọ; nigbati Mose si gbadura si OLUWA, iná na si rẹlẹ.
Num 11:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni àwọn ènìyàn kígbe sí Mose, Mose sì gbàdúrà sí OLúWA iná náà sì kú.
Num 11:2YCE(Yoruba Bible)
Àwọn eniyan náà sì ké tọ Mose wá fún ìrànlọ́wọ́. Mose gbadura fún wọn, iná náà sì kú.