Num 10:1-2
Num 10:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
OLUWA si sọ fun Mose pe, Iwọ ṣe ipè fadakà meji; iṣẹ́-ọnà lilù ni ki o ṣe wọn: iwọ o si ma fi wọn pè ajọ, iwọ o si ma fi wọn ṣí ibudó.
Pín
Kà Num 10OLUWA si sọ fun Mose pe, Iwọ ṣe ipè fadakà meji; iṣẹ́-ọnà lilù ni ki o ṣe wọn: iwọ o si ma fi wọn pè ajọ, iwọ o si ma fi wọn ṣí ibudó.