Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Num 1:2YBCV(Bibeli Mimọ)
Ẹ kaye gbogbo ijọ awọn ọmọ Israeli, nipa idile wọn, nipa ile baba wọn, gẹgẹ bi iye orukọ, olukuluku ọkunrin, nipa ori wọn
Pín
Num 1YBCVNum 1:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ka gbogbo àgbájọ ènìyàn Israẹli nípa ẹbí wọn, àti nípa ìdílé baba wọn, to orúkọ wọn olúkúlùkù ọkùnrin ní ọ̀kọ̀ọ̀kan.
Pín
Num 1BMYONum 1:2YCE(Yoruba Bible)
“Ẹ ka iye àwọn ọmọ Israẹli, ní agbo-ilé agbo-ilé, ati ìdílé-ìdílé; kí ẹ sì kọ orúkọ gbogbo àwọn ọkunrin sílẹ̀ ní ọ̀kọ̀ọ̀kan.
Pín
Num 1YCE