Neh 4:9 - Compare All Versions
Neh 4:9 YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn awa gba adura wa si Ọlọrun wa, a si yan iṣọ si wọn lọsan ati loru, nitori wọn.
Pín
Neh 4 YBCVNeh 4:9 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n àwa gbàdúrà sí Ọlọ́run wa, a sì yan olùṣọ́ ọ̀sán àti ti òru láti kojú ìhàlẹ̀ yìí.
Pín
Neh 4 BMYONeh 4:9 YCE (Yoruba Bible)
Ṣugbọn a gbadura sí Ọlọrun wa, a sì yan àwọn olùṣọ́ láti máa ṣọ́ ibẹ̀ tọ̀sán-tòru.
Pín
Neh 4 YCE