Mak 8:2
Mak 8:2 Yoruba Bible (YCE)
“Àánú àwọn eniyan wọnyi ń ṣe mí, nítorí ó di ọjọ́ mẹta tí wọ́n ti wà pẹlu mi, wọn kò ní ohun tí wọn yóo jẹ mọ́.
Pín
Kà Mak 8Mak 8:2 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ãnu ijọ enia nṣe mi, nitoriti o di ijọ mẹta nisisiyi ti nwọn ti wà lọdọ mi, nwọn kò si li ohun ti nwọn o jẹ
Pín
Kà Mak 8