Mak 4:41
Mak 4:41 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ̀rù ńlá bà wọ́n. Wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí bi ara wọn pé, “Ta ni èyí, tí afẹ́fẹ́ ati òkun ń gbọ́ràn sí lẹ́nu!”
Pín
Kà Mak 4Mak 4:41 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹru si ba wọn gidigidi, nwọn si nwi fun ara wọn pe, Irú enia kili eyi, ti ati afẹfẹ ati okun gbọ́ tirẹ̀?
Pín
Kà Mak 4