Mak 2:27-28
Mak 2:27-28 Bibeli Mimọ (YBCV)
O si wi fun wọn pe, A dá ọjọ isimi nitori enia, a kò dá enia nitori ọjọ isimi: Nitorina Ọmọ-enia li oluwa ọjọ isimi pẹlu.
Pín
Kà Mak 2O si wi fun wọn pe, A dá ọjọ isimi nitori enia, a kò dá enia nitori ọjọ isimi: Nitorina Ọmọ-enia li oluwa ọjọ isimi pẹlu.