Mak 14:9
Mak 14:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Lóòótọ́ ni mo wí fún un yín, níbikíbi tí wọ́n bá ti wàásù mi, ní gbogbo ayé, wọn kò ní ṣe aláìsọ ohun tí obìnrin yìí ṣe pẹ̀lú ní ìrántí rẹ̀.”
Pín
Kà Mak 14Mak 14:9 Bibeli Mimọ (YBCV)
Lõtọ ni mo wi fun nyin, Nibikibi ti a o gbé wasu ihinrere yi ni gbogbo aiye, nibẹ̀ pẹlu li a o si rò ihin eyi ti obinrin yi ṣe lati fi ṣe iranti rẹ̀.
Pín
Kà Mak 14