Mak 14:22
Mak 14:22 Yoruba Bible (YCE)
Bí wọ́n ti ń jẹun, Jesu mú burẹdi, ó gbadura sí i, ó bù ú, ó fún wọn. Ó ní, “Ẹ gbà, èyí ni ara mi.”
Pín
Kà Mak 14Mak 14:22 Bibeli Mimọ (YBCV)
Bi nwọn si ti njẹun, Jesu mu akara, o si sure, o si bu u, o si fifun wọn, o wipe, Gbà, jẹ: eyiyi li ara mi.
Pín
Kà Mak 14