Skip to content
Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Mik 2:2YBCV(Bibeli Mimọ)

Nwọn si nṣe ojukòkoro oko, nwọn si nfi ipá gbà a: ati ile, nwọn a si mu wọn lọ: nwọn si ni enia lara ati ile rẹ̀, ani enia ati ini rẹ̀.

Mik 2:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Wọ́n sì ń ṣe ojúkòkòrò oko, wọ́n sì fi agbára wọn gbà wọ́n, àti àwọn ilé, wọ́n sì gbà wọ́n. Wọ́n sì ni ènìyàn àti ilẹ̀ rẹ̀ lára àní ènìyàn àti ohun ìní rẹ̀.

Mik 2:2YCE(Yoruba Bible)

Bí ilẹ̀ kan bá wọ̀ wọ́n lójú, wọn á gbà á lọ́wọ́ onílẹ̀; bí ilé kan ló bá sì wù wọ́n, wọn á fi ipá gbà á lọ́wọ́ onílé; wọ́n ń fìyà jẹ eniyan ati ilé rẹ̀, àní eniyan ati ohun ìní rẹ̀.