Mik 1:3
Mik 1:3 Yoruba Bible (YCE)
Wò ó, OLUWA ń jáde bọ̀ láti inú ilé rẹ̀, yóo sọ̀kalẹ̀, yóo sì rìn lórí àwọn òkè gíga ayé.
Pín
Kà Mik 1Mik 1:3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori, wo o, Oluwa jade lati ipò rẹ̀ wá, yio si sọ̀kalẹ, yio si tẹ̀ awọn ibi giga aiye mọlẹ.
Pín
Kà Mik 1