Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 9:32YBCV(Bibeli Mimọ)
Bi nwọn ti njade lọ, wò o, nwọn mu ọkunrin odi kan tọ̀ ọ wá, ti o li ẹmi èṣu.
Pín
Mat 9YBCVMat 9:32BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí wọ́n tí ń jáde lọ, wò ó wọ́n mú ọkùnrin odi kan tí ó ní ẹ̀mí èṣù tọ Jesu wá.
Pín
Mat 9BMYOMat 9:32YCE(Yoruba Bible)
Bí àwọn afọ́jú náà ti jáde, bẹ́ẹ̀ ni àwọn kan mú ọkunrin kan, tí ẹ̀mí èṣù mú kí ó yadi, wá sọ́dọ̀ Jesu.
Pín
Mat 9YCE