Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 7:23YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbana li emi o si wi fun wọn pe, Emi kò mọ̀ nyin ri, ẹ kuro lọdọ mi, ẹnyin oniṣẹ ẹ̀ṣẹ.
Pín
Mat 7YBCVMat 7:23BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni èmi yóò wí fún wọn pé, ‘Èmi kò mọ̀ yín rí, ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi ẹ̀yin oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀.’
Pín
Mat 7BMYOMat 7:23YCE(Yoruba Bible)
Ṣugbọn n óo wí fún wọn pé, ‘Èmi kò mọ̀ yín rí. Ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi, ẹ̀yin oníṣẹ́ ibi wọnyi!’
Pín
Mat 7YCE