Mat 7:21
Mat 7:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
“Kì í ṣe gbogbo ẹni tó ń pè mí ní, ‘Olúwa, Olúwa,’ ni yóò wọ ìjọba ọ̀run, bí kò ṣe ẹni tó bá ń ṣe ìfẹ́ baba mi tí ń bẹ ní ọ̀run.
Pín
Kà Mat 7Mat 7:21 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ki iṣe gbogbo ẹniti npè mi li Oluwa, Oluwa, ni yio wọ ijọba ọrun; bikoṣe ẹniti nṣe ifẹ ti Baba mi ti mbẹ li ọrun.
Pín
Kà Mat 7