Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 7:2YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori irú idajọ ti ẹnyin ba ṣe, on ni a o si ṣe fun nyin; irú òṣuwọn ti ẹnyin ba fi wọ̀n, on li a o si fi wọ̀n fun nyin.
Pín
Mat 7YBCVMat 7:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí irú ìdájọ́ tí ẹ̀yin bá ṣe, òun ni a ó sì ṣe fún yín; irú òsùwọ̀n tí ẹ̀yin bá fi wọ́n, òun ni a ó sì fi wọ́n fún yín.
Pín
Mat 7BMYOMat 7:2YCE(Yoruba Bible)
Nítorí irú ẹjọ́ tí ẹ bá dá eniyan ni Ọlọrun yóo dá ẹ̀yin náà. Irú ìwọ̀n tí ẹ bá lò fún eniyan ni Ọlọrun yóo lò fún ẹ̀yin náà.
Pín
Mat 7YCE