Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 6:32YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori gbogbo nkan wọnyi li awọn keferi nwá kiri. Nitori Baba nyin ti mbẹ li ọrun mọ̀ pe, ẹnyin kò le ṣe alaini gbogbo nkan wọnyi.
Pín
Mat 6YBCVMat 6:32BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí àwọn kèfèrí ń fi ìwọra wá àwọn nǹkan wọ̀nyí bẹ́ẹ̀ ni Baba yín ní ọ̀run mọ̀ dájúdájú pé ẹ ní ìlò àwọn nǹkan wọ̀nyí.
Pín
Mat 6BMYOMat 6:32YCE(Yoruba Bible)
Nítorí gbogbo nǹkan wọnyi ni àwọn abọ̀rìṣà ń lépa. Nítorí Baba yín tí ń bẹ ní ọ̀run mọ̀ pé ẹ nílò gbogbo wọn.
Pín
Mat 6YCE