Mat 5:7-8
Mat 5:7-8 Bibeli Mimọ (YBCV)
Alabukún-fun li awọn alãnu: nitori nwọn ó ri ãnu gbà. Alabukún-fun li awọn oninu-funfun: nitori nwọn ó ri Ọlọrun.
Pín
Kà Mat 5Mat 5:7-8 Yoruba Bible (YCE)
Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn aláàánú, nítorí Ọlọrun yóo ṣàánú wọn. Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí ọkàn wọn mọ́, nítorí wọn yóo rí Ọlọrun.
Pín
Kà Mat 5