Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 5:23YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitorina bi iwọ ba nmu ẹ̀bun rẹ wá si ibi pẹpẹ, bi iwọ ba si ranti nibẹ pe, arakunrin rẹ li ohun kan ninu si ọ
Pín
Mat 5YBCVMat 5:23BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nítorí náà, nígbà tí ìwọ bá ń mú ẹ̀bùn rẹ wá síwájú pẹpẹ, bí ìwọ bá sì rántí níbẹ̀ pé arákùnrin rẹ̀ ni ohùn kan nínú sí ọ.
Pín
Mat 5BMYOMat 5:23YCE(Yoruba Bible)
Nítorí náà bí o bá fẹ́ mú ọrẹ wá sórí pẹpẹ ìrúbọ, tí o wá ranti pé arakunrin rẹ ní ọ sinu
Pín
Mat 5YCE