Mat 5:10
Mat 5:10 Bibeli Mimọ (YBCV)
Alabukúnfun li awọn ẹniti a ṣe inunibini si nitori ododo: nitori tiwọn ni ijọba ọrun.
Pín
Kà Mat 5Mat 5:10 Yoruba Bible (YCE)
Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí eniyan ń ṣe inúnibíni sí nítorí òdodo, nítorí tiwọn ni ìjọba ọ̀run.
Pín
Kà Mat 5