Mat 4:8 - Compare All Versions
Mat 4:8 YBCV (Bibeli Mimọ)
Èṣu gbé e lọ si ori òke giga-giga ẹ̀wẹ, o si fi gbogbo ilẹ ọba aiye ati gbogbo ogo wọn hàn a
Pín
Mat 4 YBCVMat 4:8 YCE (Yoruba Bible)
Èṣù tún mú un lọ sórí òkè gíga kan; ó fi gbogbo àwọn ìjọba ayé ati ògo wọn hàn án.
Pín
Mat 4 YCEMat 4:8 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́ẹ̀kan sí i, èṣù gbé e lọ sórí òkè gíga, ó sì fi gbogbo ilẹ̀ ọba ayé àti gbogbo ògo wọn hàn án.
Pín
Mat 4 BMYO