Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Mat 4:20YBCV(Bibeli Mimọ)

Nwọn si fi àwọn silẹ lojukanna, nwọn sì tọ̀ ọ lẹhin.

Mat 4:20BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Lójúkan náà, wọ́n fi àwọ̀n wọn sílẹ̀, wọ́n sì tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.

Mat 4:20YCE(Yoruba Bible)

Lẹsẹkẹsẹ wọ́n bá fi àwọ̀n wọn sílẹ̀, wọ́n ń tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.