Mat 4:13
Mat 4:13 Yoruba Bible (YCE)
Lẹ́yìn tí ó kúrò ní Nasarẹti, ó ń lọ gbè Kapanaumu tí ó wà lẹ́bàá òkun ní agbègbè Sebuluni ati Nafutali.
Pín
Kà Mat 4Mat 4:13 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nigbati o si jade kuro ni Nasareti, o wá ijoko ni Kapernaumu, eyi ti o mbẹ leti okun li ẹkùn Sebuloni ati Neftalimu
Pín
Kà Mat 4