Mat 4:11
Mat 4:11 Yoruba Bible (YCE)
Lẹ́yìn náà, Èṣù fi í sílẹ̀. Àwọn angẹli bá wá sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n ń ṣe iranṣẹ fún un.
Pín
Kà Mat 4Mat 4:11 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nigbana li Èṣu fi i silẹ lọ; si kiyesi i, awọn angẹli tọ̀ ọ wá, nwọn si nṣe iranṣẹ fun u.
Pín
Kà Mat 4