Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Mat 3:1YBCV(Bibeli Mimọ)

NI ijọ wọnni ni Johanu Baptisti wá, o nwasu ni ijù Judea

Mat 3:1BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì, Johanu onítẹ̀bọmi wá, ó ń wàásù ní aginjù Judea.

Mat 3:1YCE(Yoruba Bible)

Nígbà tí ó yá, Johanu Onítẹ̀bọmi dé, ó ń waasu ní aṣálẹ̀ Judia.