Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 28:9YBCV(Bibeli Mimọ)
Bi nwọn si ti nlọ isọ fun awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀, wo o, Jesu pade wọn, o wipe, Alafia. Nwọn si wá, nwọn si gbá a li ẹsẹ mu, nwọn si tẹriba fun u.
Pín
Mat 28YBCVMat 28:9BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí wọ́n ti ń sáré lọ lójijì Jesu pàdé wọn. Ó wí pé, “Àlàáfíà”, wọ́n wólẹ̀ níwájú rẹ̀. Wọ́n gbá a ní ẹsẹ̀ mú. Wọ́n sì foríbalẹ̀ fún un.
Pín
Mat 28BMYOMat 28:9YCE(Yoruba Bible)
Lójijì Jesu pàdé wọn, ó kí wọn, ó ní, “Ẹ pẹ̀lẹ́ o!” Wọ́n bá dì mọ́ ọn lẹ́sẹ̀, wọ́n júbà rẹ̀.
Pín
Mat 28YCE