Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 28:3-4YBCV(Bibeli Mimọ)
Oju rẹ̀ dabi manamana, aṣọ rẹ̀ si fún bi ẹ̀gbọn owu: Nitori ẹ̀ru rẹ̀ awọn oluṣọ warìri, nwọn si dabi okú.
Mat 28:3-4BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ojú rẹ̀ tàn bí mọ̀nàmọ́ná. Aṣọ rẹ̀ sì jẹ́ funfun bí ẹ̀gbọ̀n òwú. Ẹ̀rù ba àwọn olùṣọ́, wọ́n sì wárìrì wọn sì dàbí òkú.
Mat 28:3-4YCE(Yoruba Bible)
Ìrísí rẹ̀ dàbí mànàmáná. Aṣọ rẹ̀ funfun bí ẹ̀gbọ̀n òwú. Ẹ̀rù mú kí àwọn tí wọn ń ṣọ́ ibojì náà gbọ̀n pẹ̀pẹ̀, kí wọn sì kú sára.