Mat 28:18 - Compare All Versions
Mat 28:18 YBCV (Bibeli Mimọ)
Jesu si wá, o si sọ fun wọn, wipe, Gbogbo agbara li ọrun ati li aiye li a fifun mi.
Pín
Mat 28 YBCVMat 28:18 YCE (Yoruba Bible)
Jesu wá sọ́dọ̀ wọn, ó sọ fún wọn pé, “A ti fún mi ní gbogbo àṣẹ ní ọ̀run ati ní ayé.
Pín
Mat 28 YCEMat 28:18 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Jesu wí fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, “Gbogbo agbára ni ọ̀run àti ní ayé ni a ti fi fún mi.
Pín
Mat 28 BMYO